top of page
Search

Ta lo kọ́ ẹ láti kórìíra ara rẹ̀? Who taught you to hate yourself? (Malcolm X)

Updated: Jan 27Ní ọdún 1962, Malcolm X béèrè àwọn ìbéèrè yìí lọ́wọ́ wa. Wọ́n ṣì tún ṣe pàtàkì lónìí.

In year 1962, Malcolm X asked us these questions and they are still important today.


Ta lo kọ́ ẹ láti kórìíra ara rẹ̀?

Who Taught You to Hate Yourself?


Ta lo kọ́ ẹ láti kórìíra irun orí rẹ̀?

Who taught you to hate the texture of your hair?


Ta lo kọ́ ẹ láti kórìíra àwọ̀ ara rẹ̀ tí ó mu ẹ máa fi bora kí àwọ̀ ara rẹ̀ leè fi jọ t’òyìnbó?

Who taught you to hate the color of your skin

to such extent you use bleach, to get like the white man?


Ta lo kọ́ ẹ láti kórìíra ìrísí imú ati ètè rẹ̀?

Who taught you to hate the shape of your nose and the shape of your lips?


Ta lo kọ́ ẹ láti kórìíra ara rẹ̀ láti irun orí rẹ̀ dé ìka ẹsẹ̀ rẹ̀?

Who taught you to hate yourself from the top of your head to the soles of your feet?


Ta lo kọ́ ẹ láti kórìíra èèyàn bí tí ẹ̀?

Who taught you to hate your own kind?


Ta lo kọ́ ẹ láti kórìíra ìran tìrẹ tí o ò fẹ́ràn láti wà láàárín wọ́n?

Who taught you to hate the race that you belong to so much so that you don't want to be around each other?


Rárá, kó tó béèrè lọ́wọ́ Ọ̀gbẹ́ni Mọ̀ọ́mọ́dù, ṣé o ń kọ́ni láti kórìíra, ó yẹ kí ó béèrè lọ́wọ́ araàrẹ, èèyàn tí Elédùmarè dá?

No...before you come asking Mr. Muhammad does he teach hate, you should ask yourself who taught you to hate being what God made you?


About the author:I am a black person from the diaspora who is learning the Yorùbá language to reconnect with my ancestors and decolonize my mind.

32 views0 comments

Comments


bottom of page