top of page
Search

Blackness is global (my first Yorùbá blog post)


Marcus Garvey, 1922.

Àdúláwọ̀ wà kárí ayé. Ìyàtọ̀ lẹ wà láàárín wa, ṣùgbọ́n a wá láti orísun kan náà. Ó yẹ ká fi ìyàtọ̀ wọ̀nyí sílẹ̀! Ká sì fọkànsí àwọn ìjọra tó wà láàárín wa. Bí a ṣe lè gbéra wa ga nìyí gẹgẹ bí ìran kan. Marcus Garvey sọ yìí, ni ọgọ́rùn-ún ọdún sẹ́yìn. Òótọ́ ọ̀rọ̀ ṣì ni báyìí.


Blackness is global. There are differences among us, but we come from the same source. We should put aside these differences and focus on our similarities. This is how we can elevate ourselves as a race. Marcus Garvey said this 100 years ago. It's still true now.


"Africa for the Africans at home and abroad" - Marcus Garvey


I am a black person from the diaspora who is learning the Yorùbá language to reconnect with my ancestors and decolonize my mind. This is the first of many such blog posts.


Vocabulary words:


àdúláwọ̀ - black person

- to be

kárí - around

ayé - world

ìyàtọ̀ - difference

láàárín - among/between

orísun - source

ó yẹ kí - should

fi _ sílẹ̀ - to leave/abandon

fọkànsí - to focus on

ìjọra - similarity

gbé _ ga - to elevate

gẹgẹ bí - as

ìran kan - one race

òótọ́ - truth




86 views0 comments

Recent Posts

See All
bottom of page